MyNaijaLyrics

Qdot – Orijin Lyrics

Orijin Lyrics –

Orijin Lyrics - Qdot

[Intro]
(Speaking in tongues)
Alagogo o tele wa wa’bi, o ti wa ibi kan gba lo
Oni sekere ta mu wa, o gbe olosho wo’le
Antras ko igi le’lu o omo wan l’ondo eri

[Verse 1]
E fun wa l’orijin onike o, onike o (2ce)
Emi fe so kale
Awon omo mi wo’so ti ko bale
Ara yin o bale
Chelsea a na Barca bo d’ale
Ti onike ba ti tan ke bun wa l’onigo mu o
Emi fe so kale
Awon omo mi wo’so ti ko bale
Ara yin o bale
Chelsea a na Barca bo d’ale
Ah, kini mo fa na, kini mo mu
Ebi mi, kini mo fa lele o, kini mo mu
E wa wo ishe afowo fa
A mu tutolin mefa
Pelu refnol bi mefa
Igo orijin meje o
kini mo fa lele o, kini mo mu
E wa wo ishe afowo fa
A mu tutolin mefa
Pelu refnol bi mefa
Igo orijin meje o

(Speaking in tongues)

[Verse 2]
Speaking in tongues
Oju mi yi, ese mi fi laga laga
Oju mi yi o, ese mi fi laga laga
Facebook wa n jo twitter
Trouser wa n di nicker
9ice wa n jo bouncer loju mi
E fun wa l’orijin onike o, onike o (2ce)
Emi fe so kale
Awon omo mi wo’so ti ko bale
Ara yin o bale
Chelsea a na Barca bo d’ale
Ti onike ba ti tan ke bun wa l’onigo mu o
Emi fe so kale
Awon omo mi wo’so ti ko bale
Ara yin o bale
Chelsea a na Barca bo d’ale
Ti onike ba ti tan ke bun wa l’onigo mu o
Emi fe so kale
Awon omo mi wo’so ti ko bale
Ara yin o bale
Chelsea a na Barca bo d’ale

[Verse 3]
Eli, gba gburu gbu gbu gbu gbu kako
Olorun agbaye o you are mighty
Awon olosho ode oni o they are naughty
I can see them all around me now they’re up to something
Baba s’anu omo re, ma je n gba ibi mo gba wa lo jare
s’anu omo re, ma je n gba ibi mo gba wa lo jare
S’anu omo re, ma je n gba ibi mo gba wa lo (3ce)
Olosho to fe pa mi fun moomi, ki iyen ma ya odo mi
S’anu omo re, ma je n gba ibi mo gba wa lo
Mo beru awon tan mu ogo ologo kan ma ya odo mi
S’anu omo re, ma je n gba ibi mo gba wa lo
Eyi to ma mu mi re ile ejo ko ma ya odo mi baba
S’anu omo re, ma je n gba ibi mo gba wa lo
Olosho to fe ba aye mi je ko ma ya odo mi
S’anu omo re, ma je n gba ibi mo gba wa lo
Ah gbogbo arugbo olosho kan deyin leyin mi
S’anu omo re, ma je n gba ibi mo gba wa lo
Omoge to ma ran mi lo si orun ko ma ri temi ro
S’anu omo re, ma je n gba ibi mo gba wa lo
Ki momo to bi mi lomo, ki momo j’ere mi o
S’anu omo re, ma je n gba ibi mo gba wa lo
Obinrin lo bi mi n mo shey feran obinrin
S’anu omo re, ma je n gba ibi mo gba wa lo
Gbogbo olosho n ijora, badia, shomolu, bariga hey
S’anu omo re, ma je n gba ibi mo gba wa lo
Gbogbo olosho ikorodu, ikorodu ile father mi
S’anu omo re, ma je n gba ibi mo gba wa lo
They call call me Qdot alagbe yoruba boy noni jare
S’anu omo re, ma je n gba ibi mo gba wa lo

To add notes or give explanations to "Qdot – Orijin Lyrics", highlight any line or word and click "Annotate".
Orijin Lyrics - Qdot

VIEW ALL LYRICS TO SONGS BY: